AWỌN KOKO AMUYẸ IKÀKÚN1

  • Ọjọ ori 16 tabi jubẹẹlọ, pẹlu akọsilẹ iwadii arun sọjọdọlẹ (HbSS, HbSC, HbS/β0 thalassemia, HbS/β+ thalassemia, tabi awọn orisii other sickle cell syndrome variants sẹjẹdọlẹ yooku)
  • O keere tan isoro irora sejẹdọlẹ 2 ti kosi ju 10 lọ ninu awọn osu 12 to kọja saaju ki wọn to gba
    • Ti o tumọsi asiko irora to gboro, aya riro to gboro, okó lile pipẹ, tabi ẹjẹ didi ninu ẹdọ tabi ọlọ inu
  • Bi lilo hydroxyurea, oogun hydroxyurea gbọdọ wa nilẹ fun o keere tan ọjọ 90 saaju aileto

AWỌN KOKO AMUYẸ IYỌKURO1

  • Oyun tabi ifọmọlọyan
  • Gbigba eto ẹjẹ loorekoore
  • Aisedeede Hepatobiliary, aarun ẹdo lile, aarun oronro, tabi aarun kidirin lile
  • Saaju ifarahan si itọju ilera jiini tabi saaju mudunmudun eegun tabi ipaarọ sẹẹli
  • To ngba voxelotor, crizanlizumab, tabi L-glutamine lọwọlọwọ
  • To ngba itọju pẹlu awọn ohun ti ngbe hematopoietic larugẹ
  • Lilo CYP3A4/5 to lagbara ti ngbogunti tabi awọn imugberu CYP3A4 lagbara