IWIFUN ASẸKIKỌ
IFILỌ ASẸKIKỌ ATI AṢẸ RANPẸ
Gbogbo ohun ti o ri ati gbọ lori ayelujara yii (”Agbejadẹ” naa), ti o pẹlu, fun apẹẹrẹ, gbogbo akọsilẹ, iwe orukọ, fọto, apejuwe, aworan, fanran ohun, fanran fidio ati ohun-awọn fanran fidio, jẹ asẹkikọ labẹ ofin Amẹrika ati awọn ofin asẹkikọ agbaaye to see pamọ ati ipese awọn adehun. Awọn asẹkikọ ninu Agbejade jẹ ti Agios tabi ẹnikẹẹta to ti fun Agios ni asẹ awọn eronja wọn. Gbogbo Agbejade oju-ewe ayelujara yii ni asẹkikọ gẹgẹbi agbajọ isẹ labẹ ofin Amẹrika ati awọn ofin ati adehun aṣẹkikọ agbaaye to ṣee pamọ. Agios lo ni asẹkikọ ninu isaayan, isakoso, eto ati igbelaruge Agbekalẹ naa. O le gbaa silẹ, fii pamọ, se atẹjade ati sẹda awọn ipin yiyan ni Agbejade oju-ewe ayelujara yii, ti o ba jẹ:
- Ki o kan lo Agbejade naa lati gbaa silẹ fun ararẹ, ilo ti kiise isowo tabi lati se itẹsiwaju okoowo rẹ to niiṣe pẹlu Agios
- Mase atẹjade tabi se igbejade eyikeyi ara Agbejade lori awọn oju-ewe Ayelujara miiran lai kọkọ gba akọsilẹ iyọnda ti Agios
- Mase se atunṣe tabi fọwọkan Agbejade ni ọna kankan tabi paarẹ tabi ṣe eyikeyi atunṣe aṣẹkikọ tabi awọn ifilọ aami ọja tabi ifilọ idaniloju
Kosi ẹtọ, akori tabi inifẹsi ninu Agbejade ti a gbaa silẹ ni a ti fi ransẹ si ọ nigbati o gba Agbejade sile lati oju-ewe ayelujara yii. Agios ni awọn ẹtọ nkan ẹni ninu eyikeyi Agbejade ti o gba silẹ lati oju-ewe ayelujara yii. Ayafi ti wọn ba sọ loke kedere, o ko le sẹda, gbaa silẹ, se atẹjade, se agbejade, ṣe afihan, ṣe imuṣẹ, pin, ṣe itagba, fi ranṣẹ, tumọ, ṣe atunṣe, fikun, mudojuimọ, ṣe akojọ, dinku tabi yipada ni eyikeyi ọna miiran tabi ṣe idakọ gbogbo tabi ara Agbejade naa lai kọkọ gba aṣẹ ikọsilẹ lọdọ Agios.
Bi o ba ronu wipe eyikeyi Agbejade lori oju-ewe ayelujara yii koba asẹkikọ, aami ọja, ẹtọ ẹni tabi ẹtọ ẹlomiran, jọwọ fi atẹjisẹ imeeli ranṣẹ si asoju Agios ni info@agios.com.
IFILỌ AAMI ỌJA
Gbogbo aami ọja, awọn aami ati aworan akọle isẹ ti a s’afihan rẹ lori oju-ewe ayelujara yii (”Aami Ọja”)naa) jẹ awọn aami ọja Agios ti a forukọrẹsilẹ tabi ti a ko forukọrẹsilẹ ti Agios tabi ẹlomiran ti o fun Agios ni asẹ Aami ọja wọn. Ayafi gẹgẹbi a ba tete sọ ninu awọn ilana ati ise wọnyi, o le maa tun gbejade, se afihan tabi lo eyikeyi Aami ọja lai kọkọ gba akọsilẹ iyọnda Agios.
AWỌN IPINNU TI A KO GBERO
Agio fẹ awọn asọye ati esi nipa oju-ewe ayelujara yii. Gbogbo iwifun ati eronja, pẹlu awọn asọye, iye inu, ibeere, aworan, ati iru eyi, ti a jabọ si Agios nipasẹ oju-ewe ayelujara ni a gbero si OHUN TI KIISE ASIRI ati OHUN TI KIISE TẸNI. Fun idi eyi, a beere wipe ki o fi iwifun tabi eronja ti o ko fẹ fun wa ransẹ si wa, pẹlu eyikeyi iwifun asiri tabi eyikeyi awọn eronja atinuda ipilẹsẹ bii awọn oye-inu ọja, koodu kọmputa tabi isẹ aworan ipilẹsẹ. Nipa jijabọ iwifun tabi awọn eronja si Agios nipasẹ oju-ewe ayelujara yii, o fi ran nisẹ si Agios, ọfẹẹ, gbogbo awọn ẹtọ agbaaye, akori ati inifẹsi ninu gbogbo asẹkikọ ati awọn ẹtọ ohun ẹni miiran ninu iwifun tabi eronja ti o jabọ. Agios ti gbasẹ lati lo eyikeyi iwifun tabi eronja ti o jabọ nipasẹ oju-ewe ayelujara fun eyikeyi eredi ti o wa labẹ Ilana Ise Asiri, laisi idiwọ ati lai san idapada fun ọ ni ọnakọna.
OJU-EWE AYELUJARA ILANA ISE ASIRI
Tẹ ibiyi lati wo oju-ewe ayelujara Ilana ise Asisri Agios si ilo deta ara ẹni ti a gba nipasẹ oju-ewe ayelujara yii, eyiti a kopọ nipa itọkasi gẹgẹbi ara awọn Ilana ati Iṣe wọnyi.
AWỌN ÀSOPỌ SI AWỌN OJU-EWE AYELUJARA
Oju-ewe yii le ni opo ila si awọn oju-ewe ayelujara ti ko ṣiṣẹ nipasẹ Agios. Awọn opo ila wọnyi ni a ti pese fun itọkasi ati irọrun rẹ nikan, kosi niise pẹlu eyikeyi ifọwọsi eronja tabi isẹ ti a pese lori awọn oju-ewe ayelujara ẹlomiran tabi eyikeyi ibaṣepọ pẹlu awọn imuṣẹse wọn. Agios ko se atunyẹwo tabi dari awọn oju-ewe ayelujara wọnyi kosi ni dahun fun awọn agbejade wọn. Agios ko gba eyikeyi ojuse fun agbejade eyikeyi awọn oju-ewe ayelujara enikẹta ti o sopọ mọ oju-ewe ayelujara wa tabi awọn ọja ati isẹ iru ẹnikẹta naa. Awọn oju-ewe ayelujara ẹnikẹta (ati awọn oju-ewe ayelujara ti wọn sopọ mọ ọn) le ni iwifun ti ko peye, ti ko pe tabi ti ko ba igba mu. Agios ko se isoju kankan nipa agbejade tabi ipeye awọn eronja lori awọn oju-ewe ayelujara ti kiise ti Agios tabi awọn ọja tabi iṣẹ eyikeyi ẹnikẹta to nsiṣẹ lori awọn irufẹ oju-ewe ayelujara. O nwọlesi ati lo awọn oju-ewe ayelujara (ati awọn oju-ewe ayelujara ti wọn sopọ) ni ewu ara re nikansoso.
KIISE IPAARỌ FUN IMỌRAN ISEGUN
Iwifun ti a pese lori oju-ewe ayelujara yii kiise ohun ti a fẹ tabi daba gẹgẹbi ipaarọ fun imọran isegun ikọṣẹmọṣẹ. Maa wa imọran onisegun rẹ tabi olupese ilera to yẹ nigbagbogbo nipasẹ eyikeyi ipo tabi itọju isegun. Kosi nkankan to wa lori oju-ewe ayelujara yi ti a pinnu pe ki o wa fun imọ idi tabi itọju isegun.
IKILỌ AWỌN IDANILOJU
A ti pese oju-ewe ayelujara yi lori ipele “BI O TI WA” “BI O TI WA LARỌWỌTO”, laisi awọn idaniloju oniruuru kankan. Si ẹkunrẹrẹ iseese ilepa ofin to see pamọ, Agios ṣe ifilọ gbogbo awọn idaniloju, ṣe afihan, tumọsi tabi ipo, to pẹlu, sugbọn ko pin si, awọn idaniloju isowo, ibamu fun eredi pato kan, ati ikoba awọn ẹtọ ẹnikẹta ati awọn idaniloju aisọ to njade lati ipa ọna ibaṣe tabi ipa ọna iṣesi. Lai din awọn wọnyi ku, Agios ko soju tabi daju wipe oju-ewe ayelujara yii wa larọwọto ni pato akoko kankan tabi ibi tabi wipe imusisẹ rẹ yoo ni idiwọ tabi ti koni asise. Agios koni soju tabi ni idaniloju wipe agbejade oju-ewe ayelujara yii koni fairọsi, wọmu tabi koodu miiran to le s’akoba tabi ba awọn dukia jẹ. Bi o ba lo oju-ewe ayelujara naa tabi awọn esi eronja ni inilo fun isisẹ tabi se ipaarọ irinṣẹ tabi deta, Agios koni ojuse fun awọn iye wọnyẹn. Awọn olumulo ni ojuse lati daabobo ara wọn nipa fifi eto ti ngbogunti fairọsi sori ẹrọ ayarabiasa, imudojuiwọn ati isisẹ. Iwifun ti a gbe jade lori oju-ewe ayelujara yii le ma pe tabi ko de ojuimọ o si le ni awọn aiṣedeede tabi asise ọrọ titẹ. Agio ko se idaniloju tabi se eyikeyi isoju nipa ilo, ifọwọsi, pipe, iimudojuiwọn, igbẹkẹle tabi ipari, tabi awọn esi ilo, tabi ibọwọfun oju-ewe ayelujara yii tabi eyikeyi iwifun, eronja, iṣẹ, software, ọrọ, aworan ati opo ila to wa ninu tabi ti a raye si nipasẹ oju-ewe ayelujara yii. Nitori awọn ila isẹ ko gba iyọkuro awọn idaniloju kọọkan, awọn iyọkuru wọnyi le ma kan ọ. Agios ko beere ohun ti kiise tẹni wipe awọn eronja peye tabi a le gbaa silẹ sita orilẹ-ede Amẹrika. Aaye si awọn eronja le ma ba ofin mu nipa awọn eniyan kọọkan tabi ni awọn orilẹ-ede kọọkan. Bi o ba wọle si oju-ewe ayelujara yi lati orilẹ-ede miran ti kii se orilẹ-ede Amẹrika, o se eyi ni ewu ara rẹ ti wọn si ni ojuṣe fun ifaramọ pẹlu awọn ofin ila-iṣẹ rẹ.
GBEDEKE LAYABILITI
Ilo oju-ewe ayelujara yii wa ni ewu rẹ nikansoso. Labe bo ti wu ko ri ni Agios tabi eyikeyi awọn adari, ọfisa, osiṣẹ, tabi asoju yoo wa fun ofo tabi ijamba taara tabi laiṣetaara eyiti o jẹyọ lati tabi ni isopọ pẹlu ilo rẹ tabi ailelo oju-ewe ayelujara yii tabi igbarale eyikeyi iwifun ti a pese lori oju-ewe ayelujara yii, koda bi a ba ti gba Agios ni imọran iseeṣe irufẹ ofo tabi ijamba bẹẹ. Eyi jẹ gbedeke layability ti ko peye lẹkunrẹrẹ eyiti o kan gbogbo ofo ati ijamba oniruuru, boya taara tabi laisetaara, gbogbogbo, pataki, iṣẹlẹ, ariyanjiyan, alapẹrẹ tabi omiiran, pẹlu laisi gbedeke, pipadanu data, owo towọle tabi ere. Gbedeke layabiliti yii tọka boyalayabiliti iduro fun wa lori adehun, ikọsilẹ, ibankan jẹ, layabiliti lile tabi eyikeyi ipilẹ miiran, ati koda bi asoju Agios ti ko lasẹ ti gba imọran tabi yẹ ki o ti mọ ti awọn irufe jamba ti o seese naa. Bi eyikeyi ninu awon gbedeke layabiliti yii ba jẹ wipe ko jamọ nkan tabi ti koo se fipa mu fun idi kankan, nigba naa agbajọ layabiliti fun Agios labẹ iru layabiliti pe ti ko ba ti dinku koni kọja ọgọrun owo dọla ($100.00).
ISANPADA FUN IJAMBA TABI OFO
O gba lati gbeja, se isanpada fun ijamba tabi ofo, ati se ailewu Agios, awọn ofisa rẹ, adari, osiṣẹ ati asoju, lati ati tako eyikeyi ìbéèrè ohun tí iṣe tẹni, iṣe tabi ibeere fun, pẹlu laisi gbedeke, ofin ọlọgbọn ati owo isiro, eyiti o waye lati ilo eronja rẹ (pẹlu software) tabi rufin awọn ọrọ ajọgba. Agios yoo pese ifilọ si ọ deede nipa ìbéèrè ohun tí ise tẹni, ifẹjọsun tabi igbẹjọ eyiti o gba ifilọ ti yoo si ran ọ lọwọ, pẹlu owo ara rẹ, ni igbeja irufẹ ìbéèrè ohun tí ise tẹni, ifẹjọsun tabi igbẹjọ.
OFIN ISAKOSO ATI ILA ISE
Oju-ewe ayelujara yi ni Agios ndari ti o si nmu sisẹ lati awọn ọfiisi laarin Igbimọ Massachusetts ni orilẹ-ede Amẹrika. Eyikeyi ìbéèrè ohun tí ise tẹni ni ibamu pẹlu awọn Ilana ati Ise ati/tabi ilo oju-ewe ayelujara yii ni yoo wa labẹ isakoso awọn ofin Igbimọ Massachusetts, laisi ọwọ si ikọlu awọn ipese ofin. Nipa lilo oju-ewe ayelujara yii, o fọwọsi ila isẹ ara ẹni ni awọn ile-ẹjọ apapọ ati ipinlẹ ti Massachusetts fun eyikeyi ise to jẹyọ tabi wa ni ibamu pẹlu oju-ewe ayelujara yii, awọn Ilana ati Iṣe wọnyi tabi bi o ṣe nlo oju-ewe ayelujara yii. Awọn ile-ẹjọ apapọ ati ipinlẹ ti Massachusetts yoo ni ila isẹ lori gbogbo irufẹ awọn ise bẹẹ.
ISỌPỌ ATI AIMOJUKURO
Bi eyikeyi ipese awọn Ilana ati Ise wọnyi ko ba jamọ nkan tabi ti koo se fipa mu fun idi kankan nipa ile-ẹjọ ila iṣẹ to dantọ, awọn ipese yooku ti awọn Ilana ati Iṣe wọnyi yoo wa pẹlu agbara ati ipa lẹkunrẹrẹ. Eyikeyi ipese awọn Ilana ati Ise wọnyi ti ko jamọ nkan tabi ti koo se fipa mu fun idi kankan ni apa tabi odidi yoo wa pẹlu agbara ati ipa titi de ibiti ko jamọ nkan tabi ti koo ṣe fipa mu fun idi kankan. Kosi imojukuro ọrọ kankan niti Ajọgba yii ti yoo wa fun imojukuro irufẹ ọrọ naa tabi eyikeyi ọrọ miiran siwaju sii.
APAPỌ AJỌGBA
Ajọgba yii ati Ilana Ise Asiri jẹ apapọ ajọgba laarin iwọ ati Agios pẹlu ibọwọfun lati wọlesi ati/tabi lo oju-ewe ayelujara yii ati Agbejade naa kosi ni see tunṣe ayafi nipasẹ Agios gẹgẹbi a ti pese rẹ nibi tabi nipasẹ iwe akọsilẹ kan ti awọn ẹni mejeeji buwọlu. Agios le gbe awọn ẹtọ ati ojuse rẹ labẹ Ajọgba yii ati Ilana Ise Asiri fun ẹnikẹni nigbakugba lai sọ fun ọ tabi ki o fọwọsi.