Nipa Mitapivat
Oogun Iwadii kan Pẹlu Okun
Kinni Idi Siṣe Iwadii Mitapivat Nisisinyi
Mitapivat: ni okun lati mu ki agbara gberu sii ki o si din aisan awọn sẹẹli ẹjẹ pupa kù. Afojusun RISE UP ni lati kọ iṣe deede ati aabo mitapivat ninu titọju isoro irora ati sẹjẹdọlẹ. Bi FDA ba fọwọ sii, mitapivat yoo jẹ irufẹ itọju tuntun kan fun aarun fòní kú fọ̀la nde.
Mólékù mitapivat maa nso pọ mọ ẹnsaimu kan ninu sẹẹli ẹjẹ pupa eyi ti o wa fun ipese agbara. Eyi ni okun lati mu ki agbara gberu sii ki o si din aisan awọn sẹẹli ẹjẹ pupa kù.
Gba awọn okodoro ọrọ
Ọpọlọpọ iwifunni lo wa lode. Wa ni ominira lati beere awọn ibeere ki o ba le ni itura didarapọ mọ idanwo iṣegun naa. Bi o ba pinnu lati dara pọ, ilera ati aabo rẹ jẹ aayo akọkọ. Kẹkọọ sii ni oju-ewe Àròsọ ati Okodoro ọrọ.
Akọni Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde
Akọni Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde
MURASILẸ FUN IFARAHAN RISE UP TO KAN
Kọ sii nipa RISE UP, pẹlu alayẹ ẹkunrẹrẹ ibiwẹ, gbogbo awọn afojusun iwadii, ati koko alaye ifisi ati iyọkuro. Lẹyin naa ba awọn alaisan rẹ to yege sọrọ nipa iwadii naa.
Bi o ba ni awọn ibeere, fi imeeli ránṣẹ́ sí:
medinfo@agios.com (US)
ex-usmedinfo@agios.com (ita US)
Isanpada wa fun awọn jagunjagun o si le ma tii kopa ninu RISE UP.
A fun awọn Akọni ní gbà-má-bínú wọ́n si le ma tii kopa ninu RISE UP. Akọni Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde jẹ ọrọ kan ti a sẹda ti awujọ àìsàn fòní kú fọ̀la nde si nlo.
O ntọkasi àwọn ọlọ́dọnni ti ngbe pẹlu àìsàn fòní kú fọ̀la nde.
A ko fọwọsi mitapivat fun itọju aarun sẹjẹdọlẹ.
A ko fọwọsi mitapivat fun itọju àìsàn fòní kú fọ̀la nde.