Àwọn Àròsọ ati Okodoro ọrọ

Otitọ nìyí

 / 
Àròsọ:
Bi o ba ti dara pọ mọ idanwo kan, o ti di eniyan tí a ndán nnkan wò lára rẹ̀.

Ninu awọn idanwo iṣegun, akoyawọ ṣe koko. Idi niyẹn ti gbogbo idanwo fi maa nrii daju wipe ẹtọ awọn olukopa ni aabo nipa ifọwọsi ti a fi oye ṣe.

Iwe ifọwọsi ti a fi oye ṣe naa nsapejuwe awọn iṣẹ ṣiṣe idanwo, abẹwo, ati ewu ati anfaani to seeṣe. Kika a le ran ọ lọwọ lati ṣe ipinnu boya o fẹ dara pọ tabi o ko fẹ dara pọ. O kii ṣe ohun ti a fi ndan nnkan wo. O jẹ olukopa onimọ.

Àròsọ:
Awọn idanwo iṣegun ko han kedere nipa aabo rẹ.

Ibanisọrọ gbangba ati akoyawọ nipa aabo idanwo jẹ aayo akọkọ. Gbogbo idanwo iṣegun ni a yẹwo fun aabo ati ilana nipasẹ ajọ ilera ati aabo gbogbogbo ati igbimọ iwadii labẹ ofin ti orilẹ-ede ti ó nkopa. Awọn ẹgbẹ wọnyi nsiṣẹ lati ṣe ifidimulẹ akoyawọ pẹlu awọn olukopa nipa awọn anfaani ati ewu awọn oogun iwadii.

Fiforukọsilẹ ni idanwo iṣegun kan ko l’ewu.

Ninu awọn idanwo iṣegun, awọn olukopa maa ngba itọju tuntun to seeṣe ki a le ṣe iwadii awọn anfaani ati ewu to seeṣe, bi eyikeyii ba wa.

Bi idanwo iṣegun kan ba wa ti mo le dara pọ mọ́, dokita mi yoo sọ fun mi nipa rẹ.

Dokita rẹ le má mọ nipa gbogbo idanwo iṣegun. Ile-ẹkọ Gbogbogbo ti Ilera ti ni akopamọ ori ayelujara nibiti o ti le wa lati ri awọn idanwo to yẹ. Fun iranlọwọ sisawari awọn isayan rẹ, ba dokita rẹ sọrọ. O tun le kan si ẹgbẹ alagbawi kan tabi s’abẹwo si oju-ewe ayelujara iwifunni kan bii SCDstudies.com.

Bi mo ba darapọ mọ idanwo iṣegun kan, nko nii gba ipele itọju kan naa ti mo ngba lati ọdọ dokita mi.

Kii ṣe pe awọn olukopa idanwo ngba itọju lati ọdọ awọn osiṣẹ idanwo nikan, sugbọn lati ọdọ awọn dokita wọn pẹlu. Lara awọn idanwo ni awọn agbekalẹ ẹkunrẹrẹ, o si ma nsaba ni awọn afikun ayẹwo ati awọn afikun abẹwo.