Àtòkọ àwọn ojú ewé


Isanpada wa fun awọn jagunjagun o si le ma tii kopa ninu RISE UP.
A fun awọn Akọni ní gbà-má-bínú wọ́n si le ma tii kopa ninu RISE UP. Akọni Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde jẹ ọrọ kan ti a sẹda ti awujọ àìsàn fòní kú fọ̀la nde si nlo.
O ntọkasi àwọn ọlọ́dọnni ti ngbe pẹlu àìsàn fòní kú fọ̀la nde.
A ko fọwọsi mitapivat fun itọju aarun sẹjẹdọlẹ.
A ko fọwọsi mitapivat fun itọju àìsàn fòní kú fọ̀la nde.
Wo oju-ewe Ṣíṣe Ipinnu lati ojú ewé F’orukọsilẹ ayelujara yii fun iwifunni amuyẹ siwaju sii.
Gbogbo aaye ni o nilo ayafi bi a tọkasii.
Ikọ Agios Medical Affairs yoo kan si ọ laipẹ. Wa ni ifojusọna fun imeeli wọn (medinfo@agios.com (US) tabi ex-usmedinfo@agios.com (ita US)) ki o le gba iwifunni ti o nilo.