Gbolohun Iwọle


Iwọle dijita se pataki si Agios Pharmaceuticals. Si apa yẹn, a fẹ ki gbogbo eniyan to nsabẹwo si oju-ewe ayelujara wa ati ipese dijita lati ni ifamọra ki wọn si ri iriri to lere. Lati muki oju-ewe ayelujara wa see wọlesi, see lo, ati wulo si olukuluku to gbarale awọn imọ ẹrọ oniranlọwọ tabi awọn irinṣẹ ifisinu miiran, a ngbiyanju lati tẹle ati fojusi awọn Ilana Iwọlesi Agbejade lori Ayelujara (WCAG) 2.1 Ipele awọn ajọhun AA lori awọn Oju-ewe Ayelujara. Awọn ilana yii s’alaye bi a ti le s’agbekalẹ oju-ewe ayelujara ti o si wa larọwọto fun awọn alabọ ara eniyan tabi awọn ti wọn nlo ẹrọ iranlọwọ.
Oju-ewe ayelujara yii nlo awọn imọ ẹrọ orisirisi ti o jẹ ko wa larọwọto ni gbogbo igba.
Bi o ba fẹ lati kansi eniti o ni oju-ewe ayelujara naa. Jọwọ lo nọmba foonu yi: +1 617-649-8600.