Isisinyi ni Akoko Naa
#AkọniÀìsànFòníKúFọ̀laNde
Kẹkọọ sii nipa idanwo iṣegun nipa bibeere awọn ibeere ti ó saba máa nwaye lọwọ awọn awujọ àìsàn fòní kú fọ̀la nde.
Bi o ba ni awọn ibeere, fi imeeli ránṣẹ́ sí:
medinfo@agios.com (US)
ex-usmedinfo@agios.com (ita US)
Akọni Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde
Gbọ lati ọdọ akọṣẹmọṣẹ kan
Tẹti si awọn Dokita Ahmar Zaidi tí a ká sílẹ̀ Koodu Abayọ:
Ìkásílẹ̀ Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde kan
Isanpada wa fun awọn jagunjagun o si le ma tii kopa ninu RISE UP.
A fun awọn Akọni ní gbà-má-bínú wọ́n si le ma tii kopa ninu RISE UP. Akọni Àìsàn Fòní Kú Fọ̀la Nde jẹ ọrọ kan ti a sẹda ti awujọ àìsàn fòní kú fọ̀la nde si nlo.
O ntọkasi àwọn ọlọ́dọnni ti ngbe pẹlu àìsàn fòní kú fọ̀la nde.
A ko fọwọsi mitapivat fun itọju aarun sẹjẹdọlẹ.
A ko fọwọsi mitapivat fun itọju àìsàn fòní kú fọ̀la nde.